ÌPÍN Lyrics - Sola Allyson
Lyrics
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN O
BEFORE I WAS FORMED IN MY MOTHER'S WOMB
BẸ́Ẹ̀NI
BEFORE I WAS FORMED IN MY MOTHER'S WOMB
MO TI YÀN'YÍ O
ÌPÍN MI RÈÉ O MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ ÒUN NÌKAN NI
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN ELÉDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN ELÉDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN ELÉDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÈMI Ò TÌẸ̀ MỌ̀ MO KÀN Ń R'ÌRÌN MI LỌ NI
ÈMI Ò MỌ̀
MI Ò MỌ̀ B'Ó ṢE JẸ́
OJÚ U MI L'Ó LÀ TÍ MO FI MỌ̀
ÌPÍN NÁÀ RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
BEFORE I WAS FORMED NÍNÚ ÌYÁ À MI
L'A TI YÀN MÍ O
ÈMI NÁÀ RÈÉ O
ÒGO NI MÀÁ ṢE FÚN ỌBA T'Ó NI ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN MI
MI Ò MỌ̀ P'Ó MÁA LE B'Ó ṢE LE Ń'GBÀ YẸN
ṢÙGBỌ́N MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌDÀÀMÚ LÈ WÀ L'Ọ́NÀ ÌBÀNÚJẸ́ LÈ WÀ L'Ọ́NÀ
ṢÙGBỌ́N MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
L'ÈLÉTÒ ÌPÍN Ó TI DÁ MI PẸ̀LÚ ÌPÍN MI
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
ÀÁNÚ WÀ, ÌRÀNWỌ́ WÀ
ÀÁNÚ WÀ LÁTI ÒKÈ
LÁTI ÀGBÀLÁ ÌMỌ́LẸ̀
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ TÈMI
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
ÌMỌ́LẸ̀ TÈMI KÒ JỌ T'ẸLÒMÍÌ
Ọ̀DỌ̀ ONÍÌMỌ́LẸ̀ ṢÁÀ NÁÀ L'Ó TI WÁ
ÌMỌ́LẸ̀ TÈMI OLÚṢỌLÁ ÀṢÀKẸ́ ARẸ́SẸ̀TẸLẸ
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀. YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
KÍ ÀWỌN T'Ó BÍ MI
K'Ọ́N TÓ PÀDÉ ARA WỌN RÁRÁ
A TI YÀN MÍ O
PÉ ỌMỌ ÌMỌ́LẸ̀ L'ÈMI
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ N'ÌPÌLẸ̀ AYÉ
A TI YÀN'PÌN O
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
OHUN TÍ MO BÁ Ń'LẸ̀ Ó MÚ ÌDÀÀMÚ WÀ
ÌPÍN MI NI
SÍBÈ ÀÁNÚ WÀ
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN O
AYÉ Ń MO DÉ L'Ọ̀NÀ Á WỌ́
ÀÁNÚ WÀ SÍBẸ̀
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN O
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
MÀÁ FI Ṣ'Ẹ̀WÀ
MÀÁ FI Ṣ'ỌLÁ
S'Ọ́BA ÒKÈ T'Ó L'ỌLÁ
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
N'ÌPÌN TI DÚÓ
ỌJỌ́ Í B'Ẹ̀BẸ̀ ÀTI YỌ
ÌMỌ́LẸ̀ Í B'Ẹ̀BẸ̀ ÀTI TÀN
ÌṢẸ̀DÁ ÌMỌ́LẸ̀ L'ÈMI
MI Ò NÍ B'Ẹ̀BẸ̀ ÀTI HÀN
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
ỌJỌ́ Í B'Ẹ̀BẸ̀ ÀTI YỌ
ÌMỌ́LẸ̀ Í B'Ẹ̀BẸ̀ ÀTI TÀN
ÌṢẸ̀DÁ ÌMỌ́LẸ̀ L'ÈMI
MI Ò NÍ B'Ẹ̀BẸ̀ ÀTI HÀN
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
(ADMONITION)
YOU MUST WORK
YOU MUST WATCH
WATCH AND PRAY
WORK AND PRAY
Ọ̀RỌ̀ NI O
Ọ̀RỌ̀ ÌMỌ́LẸ̀ NI
YOU WILL WATCH AND PRAY
YOU WILL WORK AND PRAY
WÀÁ Ṣ'IṢẸ́ T' Ó YẸ K'ÓO ṢE
WÀÁ RÌNNÀ T'Ó YẸ K'ÓO RÌN
PROCESS, STEP UPON STEP
L'A MÀÁ FI DÉ'BẸ̀ YẸN
BẸ́Ẹ̀NI, ỌMỌ MÁ GBÀGBÉ O
IṢẸ́ WÀ T'ÁA MÀÁ ṢE
IṢẸ́ WÀ T'ÁA MÀÁ ṢE
ṢÙGBỌ́N SÍBẸ̀ ÌMỌ́LẸ̀ YẸN
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
I HAVE MADE UP MIND
WHATEVER COMES ON MY WAY
MÀÁ TÀN'MỌ́LẸ̀ MÀÁ TÀN'MỌ́LẸ̀
AYÉ Á RÍ MI WỌ́N Á RÍ ÌMỌ́LẸ̀ OLÓGO
(ADMONITION)
THAT THE OWNER OF TOMORROW
Ó NÍ ÌFẸ́ SÍ MI
ÌFẸ́ RERE L'Ó NI SÍ MI
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
(ADMONITION)
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
IT HAD BEEN PLANNED THAT I WILL BE LIKE THIS
ṢÙGBỌ́N MÀÁ RÌN MÀÁ RÌN L'Ọ́NÀ ÌMỌ́LẸ̀
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
Ó N'ÍBI TÍ ÌMÍSÍ TI Ń WÁ FÚN MI
ÌFẸ́ IBẸ̀ NI MÀÁ ṢE
ÌMÍSÍ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
O N'ÍBI TI ÌMÍSÍ TI MÀÁ NWA FÚN MI
ÌMÍSÍ YẸN MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
IBI ÌMỌ́LẸ̀ N'ÌMÍSÍ MI TI Ń WÁ
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
K'Ọ́LẸ̀ T'Ó SỌ
A TI YÀN'PÌN
ÌPÍN RÈÉ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
SÍ OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ ONÍÌMỌ́LẸ̀ O
ÌMỌ́LẸ̀ YÍ O
MÀÁ FI Ṣ'ÒGO
ÌRAN YÍ YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ ỌLỌ́RUN ÌMỌ́LẸ̀
ÌRAN YÍ LÁT'ORÍ I TÈMI YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ ỌLỌ́RUN OGO
ÌRAN YÍ YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ, MI Ò R'ÍRÚ Ẹ̀ RÍ ṢÙGBÓN Á T'ORÍ MI BẸ̀RẸ̀ ỌLỌ́RUN ÌMỌ́LẸ̀
ÌRAN YÍ YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ N'ÍKỌ̀KỌ̀ NÍ GBANGBA O, ỌLỌ́RUN OGO
ÌRAN YÍ YÓÒ MÀÁ Ṣ' ÀFẸ́RÍ RẸ ỌLỌ́RUN ÌMỌ́LẸ̀
ÌRAN YÍ YO MA ṢÀFẸ́RÍ RẸ ỌLỌ́RUN ÒGO
ÌRAN MI YÓÒ MÁA Ṣ'ÀFẸ́RÍ Ẹ
KÒ ṢẸLẸ̀ RÍ NI MO GBỌ́
ṢÙGBỌ́N Á T'ORÍ Ì MI BẸ̀RẸ̀
IRAN MI YÓÒ MÀÁ WÀ NÍNÚ ÌFẸ́ RẸ
ỌLỌ́RUN ÒGO
ỌLỌ́RUN ÌMỌ́LẸ̀ T'Ó JÓÒKÓ S'ÓRÍ ÒBÍRÍ AYÉ
MÀÁ ṢÈ'FẸ́ Ẹ̀ RẸ
End of ÌPÍN Lyrics - Sola Allyson
OUR MISSION
Our MISSION is to spread the gospel through the promotion
of Gospel music, Ministries, Music concerts and more.
The idea to support and promote Music Events,
Church Revivals and similar activities
within the Christian faith is what we share.
*Lyrics COPYRIGHT DISCLAIMER*
We do not own the Lyrics for any of the songs or the images featured on this website.
All Lyrics rights belong to its original owner/owners.
No copyright infringement is intended.
We STRONGLY advice you purchase tracks from outlets provided by the original owners
Contents here are for promotional purposes only.
Please Add a comment below if you have any suggestions
Thank you & God Bless you!
All Song Lyrics are the property and Copyright of the Original Owners
Songs and Images here are For Personal and Educational Purpose only!
ÌPÍN Lyrics - Sola Allyson
ÌPÍN Lyrics - Sola Allyson
ÌPÍN Lyrics - Sola Allyson
ÌPÍN Lyrics - Sola Allyson
ÌPÍN Lyrics - Sola Allyson